Smiley face

Awon Gbajugbaja Iroyin Apa-Keta

Lara awon isele Boko Haram to ba ni lokan je julo ni eyi to waye ni agbegbe Nyanya ni ilu Abuja ni ojo kerinla osu kerin odun 2014. Nibi ti aimoye awon eniyan ti won fe wo oko ati awon oloja ti won wa ohun ti won yoo je se ku iku ojiji. Iroyin yii wa lara awon gbajugbaja iroyin lori ate olayemioniroyin.com la se tun mu pada wa. Ki Edumare ba wa da alaafia pada si ilu Nigeria. Amin
 E le ka awon iroyin naa nibi
Nyanya 1
Nyanya 2
Nyanya 3
Nyanya 4 
Nyanya 5

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment