Smiley face

Idi Ti E Fi Ri Mi Nibi Ipolongo Buhari Ni YII- Atiku



Igbakeji Aare ile Nigeria nigba kan ri to tun je okan pataki ninu egbe APC, Alhaji Atiku Abubakar ti salaye wi pe oun rekoja omode oloselu eleyii ti enikan kan le fọwọ re lori waya lo si ibi ipolongo lai se wi pe won fi iwe pe oun. O ni won kii fiwe pe oun, idi pataki ti oun kii fii yọju ni yii. O ni awon nnkan wonyii ni oun ti se lalaye fun adari iponlogo idibo fun Buhari to je Rotimi Amaechi.

Ohun ti Turaki Adamawa wi ni yii :


“I campaigned for late Shehu Yar’Adua twice successfully.

“We did that of Abiola, Obasanjo and for myself.

“I am not a light weight politician, whoever needs my presence should contact and extend invitation to me.”

“They need to check the strategy they are adopting and I made that clear to the campaign DG, Rotimi Amaechi and I told him that if you don’t consult or invite me, you will not see me,” alaye Atiku

Atiku tun je ka mo ero re nipa egbe Onigbale. Ohun to wi ni yii:

“APC will win because everyone is tired with the current administration,” he said. “So, despite the challenges in APC, change will surely come.”
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment