Gomina Ipinle Abia nigba kan ri, Orji Uzor Kalu mu ijo shoki jo nibi ipolongo re kan to se lowolowo yii ni ipinle re. A gbo wi pe okunrin olowo naa tun mura a ti di Senato bayii.
E tun le wo igbe aye gomina Orji Uzor Kalu leyin igba to pari isejoba re gege bi gomina Ipinle Abia nibi o ti gbe n jaye alakata.
Orji Uzor Kalu 1
Orji Uzor Kalu 2
Orji Uzor Kalu 3
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment