Awon egbe kan ti won je ti eya Fulani ba Aare Goodluck Jonathan lalejo lonii ni ile ijoba apapo to wa ni ilu Abuja nibi won ti n fii lokan bale wi pe bi ike ni awon wa leyin re. Koda, won tun fun Aare ni iwe eri lati je baba isale won.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment