Olorun nikan lo ye nipa idunnu ti Maheeda n ri ninu fifi idi re han aye. Sugbon sa, kokojabele ni ile aye, onikaluku n se tie ni. Maheeda n fedi kiri aye, Jonathan n sare kiri bi o se ni subu, awon kan wa ise nigba ti awon kan wa ounje ti won o je sikun.
Sugbon nipa ti Maheeda, idi ni bebi naa n fe kiri aye. Aye o ni fedi han wa o! Amin
0 comments:
Post a Comment