Smiley face

Olori Ile Asoju-Sofin Nigba Kan Ri Naa Ti Kọ PDP Sile Bo Sinu APC : Ghali Na'abba Salaye Idi To Fi Koyin Si Jonathan

Olori ile igbimo asoju-sofin nigba isejo Baba Iyabo, Ghali Na'abba  ti fi egbe PDP sile bo sinu egbe Onigbale. Igbese tuntun yii lo waye lojo keedogun osu keta odun yii ni ilu Abuja.

"Mo pinnu lati fi egbe PDP sile nigba ti mo sakiyesi wi pe egbe naa ti yẹgẹrẹ kuro ninu isejọba awaarawa" oro Ghali Na'abba.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment