Mo ni mo ri ukwu to ju ukwu lo, eyin ni ko ri bẹẹ. Nje eyin ri iru ukwu bayii ri loke yii? Bi iru ukwu bayii ba gbode, o ye e ti mo wi pe ti Kim ni, omoge onibadi olokiki ilu Amerika, omoge ti n fidi pawo bi eni jẹ tẹtẹ. Mo ki yin kaabọ si abala idi Kim, Ibadi to lokiki ju lo lagbaye.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment