Won ni bi won ti n se laye ni won se lorun. To ba ri bee, a je wi pe bi won ti n se niju naa ni won se nigboro. Ti inu awon eranko inu igbo ba dun , ko si ara ti won kii da. Ni Voronezh to wa ni ilu Russia ni awon oniroyin kan ti lo se abewo si igbe aye awon eranko ninu igbo ni akoko ti yinyin n bo loju orun. Okan ninu awon kamera ti won gbe kale ni okan ninu won mugun nigba ti ekeji ju yinyin soke bi igba ti eniyan an ju ogulutu safefe.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment