Oni ojo kerin osu kerin odun ni ojo ibi Omoh Anyohlah Thitar, okan lara awon ololufe OlayemiOniroyin.Com. Ni Oruko gbogbo awon igbimo mi pata, a ki Omoh Anyohlah Thitar ku ojo ibi toni, igba odun, odun kan ni. Amin
Ẹyẹ ti o sebi adan ò si mọ nigbo.
Bi ẹyẹ aparo fogun ọdun fọsọ pipọn.
Asọ pipọn aparo ò le funfun bi ẹfun.
Omoh maa gbọ, Edumare lo fun ọ lẹwa to pọ.
Binu-binu aye won binu lori asan ni.
Edua oke lo da ọ lọla lo tun fọmọlubi sọrọ rẹ.
Bo ba lo igba ọdun laye ẹwa rẹ o ni bajẹ lailai.
Owó atọmọ yoo ma gba yun-un lọọdẹ rẹ ni.
Asẹ!
Alaafia ko si ni keyin lọla Eledumare ọba mi oke.
HAPPY BIRTHDAY!
Appreciate u soo much bros
ReplyDeletethank your your good infomation
ReplyDeletesoda pdf activation key