Smiley face

Foto: Won Ti Bere Akitiyan Lori Fiimu Onirawo Meje Tuntun

Ti alagbede ba n lurin loju kan soso, olohun ti o gba lowo irin ni. Sebi ti o ba nidi obirin kii je'Kumolu. Obirin to ba n je Kumolu a je wi pe ijamba nla kan ti mu akin ile won lo nu-un.

Olayemi Oniroyin, e wo la tun ri gbo o?
Ok now, sebi e mo wi pe Satide ti o ba dun, ati ojo Jimoh ni eniyan o ti mo bo se n lo?

Ibudo isere tiata agbelewo kan ti mo jalu lo tun soju mi baibai.

Lai se wi pe won sese n fenu salaye, bi won se n se fiimu naa fi ye ni wi pe okan lara awon sinima ti yoo migboro titi ni nigba to ba jade

Kini ni itan inu fiimu naa dale lori?
Awon wo lo wa nidi ise opolo naa?
"A story to me means a plot where there is some surprise. Because that is how life is - full of surprises." 
- Isaac Bashevis Singer
Aimoye awon aworan to se koko inu fiimu yii gan-an ni won ko jale lati fi le mi lowo. Die ti mo ri gba, pupo re je teyin itage.
Eni a n gbe iya bo wa ba ni, ko gbodo maa naga lori fensi. O le wu pupo, se e mo wi pe asiko ojo lawa? Sodiafo, e je ka ma foju sona fun akotun ise opolo eleyii to seese ko wa lara awon fiimu onirawo meje ti yoo  jade ninu Nollywood ise tiata Nigeria.

Nje e ti gbo?

A ni mo fe seinji oruko mi. Lati akoko yii lo, e maa pe mi ni Buhariyemi Oniroyin Mai Labare Duniyan.

Walahitalai mo gba yii! erkk
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment