Smiley face

Inu Awon Kan Ko Dun Bi Won Se Bura Fun Ajimobi Lonii

Arabirin kan ti oruko re n je Adenike Adeniran lo fi ero okan re han lori ero FACEBOOK lonii nipa bi Ajimobi se wole gege bi Gomina Ipinle Oyo.

Ohun ti arabirin naa wi ni yii:
"This is one of the tools he used 2 cajole them apart from rigging the last election. Hope you are still eating the rice? You voted for him all because of rice that is not upto a congo. Alatenuje gbogbo."

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment