Smiley face

Saheed Osupa Korin Fun Omidan Asa

 
Won lo kere bee ni ko koja ohun ti won le fin simu lo, se bi ata gungun ni won wi ni? Ta ba n so nipa igbelaruge Asa ile Yoruba, sorosoro ori redio bi Omidan Olayinka Ajani ti gbiyanju koja ohun enikan le ko soju iwe takada kan soso gege bi iroyin. Igba o tun fe de lade lo tun pe ode AYAJO ASA PONBELE. 

E gbo na, olorin wo lo tun moju asa bi Akorede Omo Okunola...? Osupa korin, imole nla si tan ni Ilu Ilorin Afonja.

Gbogbo aye ni won si n ki Omidan Olayinka wi pe o ku ise takuntakun nipa igbelaruge Asa ati Ede Yoruba.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment