Smiley face

Talo Sa Maanu Yii Lada Lori, Se Adigunjale Ni Abi Awon Omo Janduku?

Okunrin yii lo gbe foto apa ori re si ori Facebook. Ko so ohun kan pato nipa apa ori re leyin ope to n fi fun Oluwa Oba. Sugbon, oju apa naa fe da bi eni wi pe ada ni won sa mo maanu naa latari. Ko ma lo je wi pe awon adigunjale lo ko lu u? Edumare ko ni je ka se kon-onge aburu o.

Ninu foto isale yii, o dabi eni wi pe won ti ba a ran, oju apa naa si ti n pade, e ri wi pe oro re tope. To ba je wi pe orun re ni won sa lada nko? Ninu ohun gbogbo, e je ka maa dupe. Sugbon sa, adura ti mo koko se naa ni in fi kase re nile:  Edumare ko ni ja ka se kon-onge aburu o. Amin



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment