Smiley face

Bukola Saraki Tun Pada Ja Irawo Tinubu Lonii Nile Igbimo Asofin Agba

Bo se n sele ni ile igbimo asoju-sofin bee naa ni n sele ni ile igbimo asofin agba. Rigimo, surutu, awuyewuye, oselu eta-inu ko tan boro ni ile igbimo asofin mejeeji to wa ni ilu Abuja.

Lori esun wi pe awon kan lo yiwe ofin ilana ati agbekale ile igbimo asofin lati fi se agbateru fun iyansipo Bukola Saraki, ti won si gba wi pe eri yii ti to lati yo Saraki ilu Ilorin loye. Awon senato ti won pe fun iyoloye Saraki ni awon Senato ti won se olooto si awon asiwaju egbe APC eleyii ti Tinubu je 'godufada' gbogbo won.

Nibi won ti n dana yii lonii (28-07-15) ni awon kan ti daba fifaramo iwaloye Bukola Saraki gege bi Aare ile igbimo Asofin.

Igba ti won bere si ka iye awon senato ti won fara mo iwaloye Saraki, awon senato bi mokanlelogorin (81) ni won la won si wa leyin Saraki bi ike. E maa si gbagbe wi pe apapo omo ile ko tayo mokandinlaadofa (109).

Eyi fi ye wa wi pe awon to si wa leyin Saraki po ju awon ti won takoo lo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment