Smiley face

Oruko Awon Oba Ti Won Ti Je Ni Ile-Ife Bere Lati Ori Oduduwa

Igbagbo awon Yoruba ni wi pe ile Ife ni orirun awon Yoruba. Awon kan tile gba wi pe Ife yii kan naa ni ile aye ti bere si ni fe titi to fi fe kari gbogbo aye. Eyi ni oruko awon Oba alaye ti won ti n je ni Ile-Ife lati ori Oduduwa to je babanla awon Yoruba:


1. Oduduwa

2. Osangangan Obamakin

3. Ogun



4. Obalufon Ogbogbodirin

5. Obalufon Alayemore (Obalufon II)

6. Oranmiyan

7. Ayetise

8. Lajamisan

9. Lajodoogun

10. Lafogido

11. Odidimode Rogbeesin

12. Aworokolokin

13. Ekun

14. Ajimuda

15. Gboonijio

16. Okanlajosin

17. Adegbalu

18. Osinkola

19. Ogboruu

20. Giesi

21. Luwoo

22. Lumobi

23. Agbedegbede

24. Ojelokunbirin

25. Lagunja

26. Larunnka

27. Ademilu

28. Omogbogbo

29. Ajila-Oorun

30. Adejinle

31. Olojo

32. Okiti

33. Lugbade

34. Aribiwoso

35. Osinlade

36. Adagba

37. Ojigidiri

38. Akinmoyero (1770–1800)

39. Gbanlare (1800–1823)

40. Gbegbaaje (1823–1835)

41. Wunmonije (1835–1839)

42. Adegunle Adewela (1839–1849)

43. Degbinsokun (1849–1878)

44. Orarigba (1878–1880)

45. Derin Ologbenla (1880–1894)

46. Adelekan Olubuse I (1894–1910)

47. Adekola (1910)

48. Ademiluyi Ajagun (1910–1930)

49. Adesoji Aderemi (1930–1980)

50. Alayeluwa Oba Okunade Sijuwade Olubuse II (1980-2015)
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment