Smiley face

Alawada Baba Sala: Ipo Ilera ati Ise Opolo Moses Olaiya

Lenu ojo meta yii ni iroyin kan jade nipa bi Alawada Baba Sala se dubule aisan niluu Ilesa ti won si gbe digbadigba wa si osibitu to to wa l'Oritamefa niluu Ibadan.

Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin, Baba Sala si n gba itoju lowo, bakan naa ni ara re si ti n pada bo sipo.

Eleyii tako iroyin eleje ti awon kan an gbe kiri wi pe Baba Sala ti dagbere faye. Baba Sala si n be laye, adura wa ni wi pe ki Oluwa ba wa fun won ni alaafia to peye.

Odun 1936 ni won bi Moses Olaiya eni ti gbogbo eniyan mo si Baba Sala. Baba Asala, okan pataki alawada eleyii ti a le gba gege bi okan lara awon ipile ise tiata ile Nigeria.

Lara awon ise Baba Sala ni yii:

Orun Mooru (1982)
Aare Agbaye (1983)
Mosebolatan (1985)
Agba Man (1992, fiimu agbelewo)
Return Match (1993, fiimu agbelewo)
Tokunbo (1985, ere olosoose)
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment