Gbajugbaja onkorin ile Amerika, Nicki Minaj ti ranse ope si sabere-dowo-di-telo to ba ranse re tuntun eleyii to wo lo sode lana.
Kaba pupa ni omobirin onidi yakata naa wo, eleyii to ni lonbodi leyin. Apa aso naa gun dele, o si tun fi igbaaya le de agbade meji oyan omobirin naa.
Aso oge yii tun mu ewa re yo sii, eleyii to mu di a-ri-ma-le-e-lo fun gbogbo oju to ri I.

0 comments:
Post a Comment