Smiley face

Femi Fani-Kayode Ti Jere Oro Lara Awon Omo Nigeria: " Oju Yin Ti Pada Jaa; Olorun Mu Gbogbo Yin" - Olufemi Olukayode

Femi Fani-Kayode, Minisita fun eto irina ofurufu nigba kan ri ati alaga eto ipolongo idibo fun Goodluck Jonathan nigba eto idibo odun 2015, ti bere si ni jere oro lara awon omo Nigeria pelu bi Aare Muhammadu Buhari se n yan awon ara oke oya si awon ipo to lagbara ju ni ile Nigeria.

Gege bi oro amofin agba ile Naijeria, eni to yi oruko re pada si Olufemi Olukayode nikete to bori esun jegudujera ti ajo EFCC fi kan-an nile ejo, so wi pe "Change" ti awon omo Naijeria n beere fun naa ni owo won ti te yii; asiko si ni yii fun won lati maa je igbadun re bi eebo se n gbadun siga.

Atejade ti omokunrin naa fi sita laaro yii. ni yii:

"1. President of the Federal Republic of Nigeria - north.

2.Senate President- north.

3. Speaker of the House of Representatives- north.

4. Chief Justice of the Federation- north.

5. President of the Court of Appeal- north.

6. Chief Justice of the Federal High Court- north.

7. Secretary to the Federal Government- north.

8. Chief of Staff to the President- north.

9. Chief of Army Staff- north.

10. Chief of Air Staff- north.

11. Comptroller General of Customs- north.

12. Director-General of State Security Services (SSS)- north.

13. National Security Advisor- north.

14. Director General NIMASA- north.

15. Chairperson of the Independant Electoral Commission (INEC)- north.

16. Comptroller-General Immigration- north.

17. Accountant-General of the Federation - north.

18. Commander of Civil Defence Corps- north.

19. Chief Security Officer to the President- north.

20. ADC to the President- north.

21. Principal Secretary to the President- north.

22. Senior Special Assistant to the President on media- north.

23. Chairman of the EFCC- north.

24. MD Nigerian Ports Authority (NPA)- north.

25. Head of Service north.

26. DG Nigerian Broadcasting Commission- north.

27. Chairman NDLEA- north.

Awon omo Naijeria n fe "iyipada" a si ti ri i. Enikeni ko gbodo fejo sun wi pe ko te oun lorun nitori ohun ti awon eniyan wa beere fun ni won ri. Opolopo wa taa kilo fun won wi pe awon nnkan wonyii nii pada bo wa sele ni won on bu nigba ti awon kan ko aida nipa wa. Nibayii, a ni lati jere ise owo wa fun odindin odun merin. Mo ki yin kaabo si Nigeria tuntun, mo si ki yin kaabo si 'Iyipada' tuntun". - Femi Fani-Kayode

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment