Ibudo awon eniyan ti Boko Haram So di alailara ati alainile lori latari ijamba ati ikolu Boko Haram ni yii ni Maiduguri to wa ni Ipinle Borno.
E le biliifu wi pe sobiri ti won fi n re ile ni won fi n bu ounje fun awon omo eniyan.
Ki Edumare ba wa mu fitinati kuro lorileede Naijeria. Amin
Home / Uncategories / Foto Ohun To N Sele Ni Ibudo Awon Ti Boko Haram So Di Alailara, Alaini Nnkankan Niyii
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment