Ijamba oko niluu Akure: oko naa jabo lati ori afara sinu odo nigba ti bireki re ko mu mo. Pupo ninu awon afara wa lo je wi pe won ko ni irin legbeegbe mo bi ti tele lati da nnkan duro lati jabo. To ba je wi pe irin wa legbe afara yii ni, oko naa ko ba ti ma jabo eleyii ti yoo din ijamba naa ku.
Se iru awon afara bee ko si ladugbo yin sa?
@OlayemiOniroyin
www.olayemioniroyin.com
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment