Tai Solarin dilu nla
Tai Solarin ile ẹkọ nla to dilu nla.
Ibi ọgbọn gbe pamọ si.
Arọni imọ ti n ja ni laya bi oke.
Gbékanlùkan isẹ ọpọlọ to fakíki.
Kinihun o jẹran ikaṣi.
To ba jọ bi irọ,
Ẹniso n'Ijgun nibi ise akada gbe gbona bi ajere.
Iba fun dokita ti n fi efun gbomola ni kilaasi.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment