Toyin Aimakhu ti pada si ile oko re, Adeniyi Johnson, eleyii to wa ni agbegbe Obadore, Ajah leyin igba to binu jade latari bo se ka oko re mo asemase pelu obirin mi-in. Igba keji re e ti 'surutu' yoo maa waye ninu igbeyawo Toyin Aimakhu sugbon to tun pada yori si ebute yiyanju.
http://www.facebook.com/photo.php?fbid=884408384978379&set=gm.1041598825891426&type=1
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment