Omobirin yii lo je okan ninu awon omo oloye kan lapa ile yibo. Ojo igbeyawo re lo gba lati si oyan re sile goloto bayii latari ati samulo asa/isese tabi ilana orisa kan ti won sin nidile won.
Sugbon sa, ibeere ti opo awon eniyan n beere ni wi pe se gbogbo ohun to wa ninu asa naa lo se koko laye ode oni?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment