Smiley face

Awada Kerikeri: Awon ole meji ti won lo fo banki

Awon ole meji ja ilekun banki kan loru ojo kan, won si n si awon seefu wo. Ninu akoko, yugooti bi i meloo kan ni won ri nibo, kò s'ówó. Won to yugooti naa wo, o ti kan lenu.

Won sikeji wo. Yugooti ni won tun ri nibe, won tun wo, won si ri wi pe, iyen daa lenu die. Sugbon ko tun s'owo nibe.

Won tun siketa, yugooti naa lo wa nibe.

Okan ninu won koju sikeji re, o ni "John, ki lo de to o lo sita. Ko o lo woo boya banki la fo looto, ki o si jokoo lati gbadun yugooti eyi to dun yi.

Leyin iseju die John pada de. O ni "A o kuku sile ya, banki la wa!"

Ekeji re ni "Ki gan-an ni won ko sara patako akole re?"
 
"Sperm Bank ilu New York!"
 
Akoba gaaaafara!!!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment