E wa wo bobo to fi tattoo ya Davido si aya re Olayemi Oniroyin 10/22/2015 08:57:00 pm Amuludun Edit Davido pada pade bobo to fi tattoo ya aworan omo baba olowo si igbaaya re. Ebun ti Davido fun naa ni alakorun ti won fi goolu se. O si so fun bobo naa wi pe awon ti di abi kan naa. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS "Ojú tí Nìyí, Toyin Abraham ti...Foto ètò ìsìnkú Aisha Abimbola nílù...Ìrántí ọdún kan Moji Olaiya wáyé lẹ... E wa wo bobo to fi tattoo ya Davido si aya re Reviewed by Olayemi Oniroyin on 10/22/2015 08:57:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment