Funke Akindele ti pada si ni sere idaraya eleyii to n se lati din ara sisan re ku. Awon obirin onise tiata maa n se eleyii lati mu ara awon wa ni ipo odo, eleyii to se pataki si irufe ise ti won yan laayo.
Owuro yii ni Funke Akindele se afihan aworan yii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment