Ti eyin ko ba tii ra iwe Iroyin Owuro to jade lose yii, a je wi pe iroyin ku sibi kan te e ti gbo.
Lati ori oro oselu de amuludun, awon oro to n lo ati igbelaruge asa ati ise Yoruba; gbogbo re lo kun fofo bi ataare.
Die ni yii lara awon koko iroyin to jade:
*Orangun yari mo Aregbe ati Owa Obokun lowo
*Alison-Madueke ko si panpe Buhari niluu London
*"Ijoba ibile wa kii fun Tinubu ni owo kankan"- Alaga kansu lo so bee
*Odun Ominira: Okan awon omo Naijiria tun taji si orileede won.
*"Obe didun ati ere ori beedi ni mo maa fi n mu oko mi mole" - Ronke Osodi-Oke
E ra iwe Iroyin Owuro ti ose yii lati ka awon ojulowo iroyin yii ati awon mii. Ogorun-un naira pere ni. Aye gbogbo wa yoo toro bi omi a fowuro pon o. Amin #IroyinOwuro deeeee!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment