Leyin odun kan ti Kehinde Osuolale dagbere faye, iroyin mi-in tun ti kan wa wi pe ikeji re, Taiwo naa ti lo ba ikeji re lajule orun.
Ohun ti a gbo ni wi pe ilu Abuja ni Taiwo ku si.
Titi di akoko yii, Olayemi Oniroyin ko ti le so pato boya otito ni isele nigba ti iwadii si n tesiwaju.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment