Ogbon ti awon omoge iwoyii tun da ni yii. Igba kan ni won dogbon ka ko foomu sidi, kidi won o le ta sita, ko si ri gelete bi aso okirika ti won di kale.
Idi omoge mi-in o ri bi apoti NADECO, eni ba tusu de isale ikoko ni o ri asiri ohun ti n mbe labe aso.
Sugbon loteyii, opon won ti sun siwaju. Ti e ba ri omoge ti igbaaya won ta sita bi isu Abuja, abi eyi to yo sobolo bi ogede agbagba, ogbon ti won da ni yii.
Awon oyinbo asaraloge ti se roba kan eleyii to dabi omu. Roba yii ni won o koko wo ki won o to wo komu. Ti won ba wo komu ni gbogbo re yoo duro soke ti o si tun ri rekete.
E tie gbo na, ki lo kan mi ninu ohun ti won ko saya? Ejoelejo se wa ka mi nisan bi eleyii?

0 comments:
Post a Comment