Lose to koja ni iroyin nipa iku Taiwo Ibeji Oran fe si wa leti, e le ka iroyin naa NIBI
Iroyin naa ti fidi mule bayii. A si tun gbo wi pe won ti sin Taiwo sinu ile re to wa ni ipinle Osun. Isele yii lo waye leyin odun kan ti Kehinde re dagbere faye.
Taiwo fi omo kan sile saye lo eleyii ti aya re igba kan, Folake bi fun un.

0 comments:
Post a Comment