Eniyan le fi ebi kose owo, sugbon ko rorun lati febi kawe. Wahala igo ni o pa alasuota. Ise akanse, ka ji kawe loru, lo soke lo sode, ka sare wo kilaasi losan pon ganrin-ganrin ni o je komo ile iwe o nisimi.
Bi won ba wa jade, ayo nla ni.
Okan ninu awon omo Poli to wa ninu Ibadan, Shina Shiba, lo se afihan foto ati akole yii:
"Finally log out from polystressnic(polytechnic) Ibadan"
Adura mi wi pe ki Edua oke ba mi so ona won dayo, ki won ri taje se, ki ona won o la sire. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment