Awon adigunjale yinbo mo oloyun niluu Ogun Olayemi Oniroyin 11/19/2015 08:18:00 pm Iroyin Edit Awon adigunjale yawo Agbara Industrial Estate to wa nipinle Ogun laaaro oni. Won si se awon eniyan bi ose si n soju nigba ti won tun kolu banki to wa ni agbegbe naa. Obirin oloyun kan naa wa lara awon eniyan ti won sagbako isele buruku naa. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS "Bàbá mi má ń fẹnu fà ọyàn mi,...Gani Adams náà tí kàwé gboyè ni LAS...Meji nínú àwọn olè Ofa tí de òpin ì... Awon adigunjale yinbo mo oloyun niluu Ogun Reviewed by Olayemi Oniroyin on 11/19/2015 08:18:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment