Smiley face

Awon sisi-mama ti won fe maa sebi omoge

A fi ki Olorun saanu mi l'Eko yii ni o. Orisiirisii loju mi n ri nijoojumo.Awon eniyan si ti fe somi lenu.  [Olayemi Oniroyin, ki lo tun ri?]

 E wo ni mi o ri, eyin naa e wole kee wenu oko now. Nigba ti adelebo ba tun fe maa sebi omoge. Eniwee, oko madaamu yii ni mo fe ri na. Mo niidi lati ri maanu to fe sile bi iyawo.

Eyin temi, e ku Sande toni
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment