Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo? Olayemi Oniroyin 11/15/2015 06:42:00 pm Iroyin Edit Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, won ri wi pe won ti yo oju re sa lo. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Dangote kò àádọ́jọ (150) ọkọ̀ kalẹ ..."Bàbá mi má ń fẹnu fà ọyàn mi,...Gani Adams náà tí kàwé gboyè ni LAS... Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo? Reviewed by Olayemi Oniroyin on 11/15/2015 06:42:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment