Gege bi oye yin nipa fiimu Naijiria, sebi gbogbo wa naa la n wo fideo agbelewo, kin ni e lero wi pe o le sokunfa ohun to sele si Muyiwa Ademola nibi? Kin ni awon ohun to le bi ki iru isele yii sele si akopa inu ere ori itage?
O ya, e bere si ni ko sitori ti yin oo
E ka ohun ti awon eniyan so NIBI
0 comments:
Post a Comment