Awon omo Yibo ti bere si ni soko oro si iran Yoruba to ri wi pe won fe pin kuro ninu orileede Naijiria. Won fe da Biafra sile, won ni awon ko ba Naijiria se mo. E dakun, e wo ni ti Yoruba ninu oro yii? Kilode ti won ko ja ija ti won ja lakoko yii nigba ti omo won wa lori oye? www.olayemioniroyin.com
http://www.facebook.com/photo.php?fbid=912946625457888&set=gm.1079320158785959&type=3
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment