Odun lo sopin, eni Edua Oke pamo nikan lo yege. Sugbon nipa temi ati awon ololufe mi, a ko ni padanu enikeni lase Eledumare. Ase
Lori eyi ni i ti ma fi yin sile lati je igbadun orin Edaoto to pe ni Somi Edumare.
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
11/15/2015 10:18:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment