Olayinka Joel Ayefele ti pada si yara agbara orin lati
gbe orin tuntun jade fun awon ololufe re kari aye. Gege bi awon ololufe
orin Gospel Tungba se mo, ti odun tuntun ba ti n sun mole ni Ayefele,
eni ti aare ana, Goodluck Jonathan fi ami-eye M.O.N.dalola, maa n gbe
awo orin tuntun jade.
Ogbeni David Ajiboye, agbenuso fun Ayefele lo kede eleyii nigba to n salaye akitiyan ti alase ati oludari ile ise Fresh Radio n se lati te awon ololufe re lorun doba. Awo tuntun ti won ko ti kede akole re yii la lero wi pe yoo jade kii odun keresimesi to wole de.
Ayefele, eni ti awon kan tun feran lati maa pe ni OJA tun fi kun un wi pe alujo inu awo orin oteyii tun maa yato si ohun ti awon eniyan mo tele. Nitori wi pe ise ti yato, alujo si ti sun siwaju.

0 comments:
Post a Comment