Olayemi omo Olatilewa |
Olayemi, odun to n bo yii, odun emi ati iwo ni. Eyin e fota sile ki won ma gbogun. E fika eniyan sile ki won ma soogun. Mo tile tun gbo wi pe awon kan tun lo n bogun onire. Sugbon igbagbo mi mbe ni Akogun ode orun.
Jagunjagun ti kii roju ogun ko to segun. Oba mi erujeje ti n lo niwaju to tun un bo leyin.
Iba ni i ma se lojo gbogbo.
Mo wa dupe lowo awon eniyan ti won ka iroyin wa losan-an loru, awon onibara wa ati awon eniyan ti won fe wa kari aye.
Olayemi Oniroyin dupe. Odun ayo ni gbogbo yoo se.
Alekun owo, omo, ayo, alaafia ati igbega. Amin
E ku odun!
0 comments:
Post a Comment