Gbogbo eto ti to bayii fun ileewe giga ti ijo Mountain of Fire and Miracles Ministries (MFM) eleyii ti won pe ni Mountain Top University lati bere eko kiko fun awon akekoo lojo Monde ose yii, 21/12/15.
Eto ibere eko kiko ifafiti tuntun yii ni yoo bere pelu ayeye igbaniwole awon akekoo eleyii ti yoo waye lojo Monde kan naa.
Ikede tuntun yii lo jade lenu oga agba fun ile iwe naa, Ojogbon Elijah Ayolabi, nigba ti n ba awon oniroyin soro.
Gege bi akojopo iroyin Olayemi Oniroyin, Ojogbon Ayolabi ni awon akekoo bi aadorinlerugba (270) ni awon yoo maa se ayeye igbawole fun lojo Aje to n bo yii. Eleyii ti won si maa gba won si elekajeka abala eko kiko to wa ninu ogba ileewe tuntun naa.
Yato si eleyii, lara ayeye ti yoo tun waye ni sisi gbongan nla kan to wa ninu ogba MFM Prayer City, Kilometre 12, Masose Eko-Ibadan, Ibafo.

0 comments:
Post a Comment