Smiley face

Gomina ipinle Rivers pon Baba E. A. Adeboye le niluu Pota

Gomina Nyesom Ezenwo Wike ti ipinle Rivers se aponle Pasito E.A. Adeboye nigba to se abewo sii lofiisi re to wa niluu Pota. Baba Adeboye wo ilu Pota lati se abewo si awon omo ijo re to wa ni ipinle naa, eleyii lo tun lo lati se e-n-le-beun si gomina.






Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment