Onise ara ni Olorun oba. Omobirin alaboyun kan lo bere si ni robi
ninu Keke Maruwa ni akoko ti won gbe lo si ile iwosan lati lo bimo niluu
Enugun.
Eyi to ju ibe ni wi pe, ojo odun lo tun wa
bosi(1/1/16))nirole patapata. Awon osise ile iwosan alabode ti won fe
gbe lo gan-an ti lo sile odun.
Sugbon lona ara ati iyanu, obirin adelebo kan ti n
koja lo sun mo alaboyun naa nigba ti oko re n keboosi "E gba mi o. Taani
yoo ran mi lowo" bonu.
Omobirin adelebo naa tu eru omo ti alaboyun naa gbe
dani, o mu awon nnkan eroja jade, o si gbebi omo naa ninu Keke Maruwa ti
won fi n gbe lo si osibitu.
Olorun fun obirin adelebo naa se to bee gee to je wi pe irorun ni gbogbo re jasi.
Omo wa laye, iya wa laye gbogbo won pata ni won sodun idunnu nidile won.
0 comments:
Post a Comment