Lati gbogun ti aisan ejeruru ti awon eleyinbo n
pe ni hypertension, awon eroja ti a ma lo niwon yii:
1 Ayu meta
2 Igo omi osan wewe tabi grape
3 Omi agbọn
4 Igo oyin kan
1 Ayu meta
2 Igo omi osan wewe tabi grape
3 Omi agbọn
4 Igo oyin kan
Bayii ni a se ma pese oogun naa:
A ma lọ odindi ayu meta papọ. Leyin eyi la ma da sinu igo ọsan wẹwẹ tabi omi grape kan fun ọjọ mẹta.
Ti a ba se eleyii tan, leyin naa ni a ma da omi agbọn (coconut) mẹta tabi marun-un si i, eleyii nii se pelu bi omi agbọn naa ba se pọ.
Ti omi agbọn naa ba pọ daadaa, mẹta ti to. Leyin eyin ni a ma da igo oyin ogidi (honey) kan sii.
Bi a se ma lo ni yii:
Gilaasi kan ni aarọ ati lalẹ fun odindi ọsẹ meji. Leyin ti a ba ti lo eleyii tan.
A ma wa ito oju igbin pupo eleyii ti a ma po mọ igo oyin kan. A ma mu sibi meji ni ẹẹmẹta lojumọ.
Olayemi Oniroyin kii se onisegun, iwadii lasan ni mo se lọwọ awon agba. Edumare to jẹ oluwosan, yo mu gbogbo wa lara da.
Enter your comment...amin aisan koni Sewa ejowo EBA mi se iwadi Ogun ti eniyan le lo si giri omo kekere
ReplyDeletehttp://www.olayemioniroyin.com/2016/01/bayii-ni-e-se-le-se-iwosan-fun-omo-to.html
Delete