Mr. Lolo Paso |
Okunrin
kan to pe oruko ara re ni Mr Lolo Paso, ti n ta rekoodu ni ibudoko Irawo to wa
ni oju ona Ketu si Ikorodu lo se alaye bi o se nife Pasuma to fun iwe IROYIN
OWURO. Eleyii to fi je wi pe, ko ta
rekoodu kankan yato si ti Wasiu Alabi Pasuma Oganla lo.
Okunrin
naa ni ti oun ba ka ale lori iyawo oun, ti oun wa n binu, o ni ti won ba fi
rekoodu Pasuma si i, oun yoo se idarijin fun awon mejeeji patapata.
Gbogbo
igba ni okunrin yii ma n jo niwaju soobu re to ba ti fi rekoodu Pasuma sii lati
fi gbe orin naa laruge. Ti gbogbo eniyan ti n lo ti n bo yoo si ma fi seran wo.
Ninu alaye re lo ti so wi pe, oun ti ba
Pasuma mule, ati wi pe, rekoodu re nikan ni oun yoo maa jo si, ohun si ni oun
yoo maa ta nigbo ojo aye oun.
E
gbiyanju ke e ra IROYIN OWURO ose yii fun iroyin lekunrere nipa Mr Lolo Paso.
0 comments:
Post a Comment