Kosi ohun ti okunrin n se ti obirin o le se. Obirin yii ni i fi okada sise aje niluu Ibadan nile Oluyole, ilu Oba Saliu Adetunji (Aje Ogungunniso 1).
A ti wi pe, gege bi oro I.K. Dairo, "Ise nise n je. Eni jale lo bomo je." Obirin to n ta ara re nitori owo ni ko se ohun to dara.
Awon akikanju obirin n sise aje lati fun omo won lounje. Edumare, ba wa fi ibukun sise won.
Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment