Oserebirin Foluke Daramola |
Laipe yii ni oserebirin,
Foluke Daramola-Salako fi ero re han fun awon oniroyin nipa bi awon eniyan se
maa n fi eru aya re se apejuwe re. Foluke se alaye iru isesi awon eniyan yii gege
bi ohun to ma n fa edun okan fun un lopo igba.
“O maa dun mi ti awon
eniyan ba fi eru aya mi se apejuwe mi. Nitori aimoye nnkan pataki lo ni i se
pelu igbe aye mi yato si aya ti awon eniyan ri. Mo je alarojinle eda, mo si nife imo lopolopo.
Sugbon ti awon eniyan ba ronu kan Foluke, ohun to ma n wa si won lokan ni eru
aya. Emi ri aya mi gege ebun lati odo Olorun. Mo si ti dagba to lati mo riri re
gege bi o ti ri," Foluke se alaye naa bee.
ERU AYA RE YEN AWON TI WON KO MA IYI RE NI WON MA FI BU AWA OKUNRIN KAN WA TO JE PE OUN TI A NIFE SI NI YEN
ReplyDelete