Inu madaru ni awon kan ti n jaye bi eni je isu. Nibi ko baje lawon ti n sodun yalayolo. Ota ilu ni won, bi won se wa loke ni won wa nisale.
Edumare ba wa ko si won ninu ki won yi pada. Sugbon ti won ko ba yipada...
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment