King Rokan: Igba Ope |
Ojo aboki ti pe ni Sabo, ona jin. O ti pe ogun odun bayii ti King Rokan ti n jise ori ran waye wa se. Ayeye ogun odun ti Rokan ti n korin to gbamuse yii ni yoo ma fo kiri agbaye bere lati ilu Naija lo si ilu Amerika, Biritiko ati orileede Ireland.
Ayeye ogun odun ti King Rokan ti n korin yii ni yoo ma waye pelu ifilole awo orin tuntun to pe ni Igba Ope. Aimoye awon olorin jankanjankan bi K1 de Ultimate, Saheed Osupa, King Sunny Ade, Obey Commander ati aimoye awon olorin ni won yoo ma peju-pese sibi ayeye naa lati ba King Rokan gbe igba ope. Ojo kejo osu kerin ni ariya yii yoo ti ma san yungbayungba titi wo ojo kejo osu karun-un odun taa wa yii.
King Rokan, kanrinkese nigba re yoo ma wa lojude. Ase
0 comments:
Post a Comment