Home /
Esin
/
E ku ojo isimi: Okunkun ko le bori imole
E ku ojo isimi: Okunkun ko le bori imole
- Ni àtetekọse ni Ọ̀rọ wà, Ọ̀rọ si wà pẹlu Ọlọrun, Ọlọrun si ni Ọ̀rọ na.
- Oun naa ni o wà ni àtetekọṣe pẹlu Ọlọrun.
- Nipasẹ̀ rẹ̀ ni a ti da ohun gbogbo; lẹyin rẹ̀ a ko si da ohun kan ninu ohun ti a da.
- Ninu rẹ̀ ni ìye wà; ìye naa si ni imọlẹ̀ araye.
- Imọlẹ na si n mọlẹ ninu òkunkun; òkunkun naa kò si bori rẹ̀.
Iwe Johanu 1:1-5
E ku ojo isimi: Okunkun ko le bori imole
Reviewed by
Olayemi Oniroyin
on
5/08/2016 07:55:00 am
Rating:
5
0 comments:
Post a Comment