Aso oge awon amuludun ko tii pe lai si goolu gidi to je oju ni gbese. Eleyii ti won yoo wa sowo, wa sorun. Awon mii tile ma n be won ni akanse goolu ni sise bi iru eyi ti Mercy gbe sorun yii. Ju gbogbo re lo, iwontunwonsi ni gbogbo nnkan, ti goolu ba po lapoju kii gbayi.Sugbon ti Mercy yii gbayi, bakan naa lo se regi orun re.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment